YOR 诗篇 章 97

诗篇 97

YOR · 比较 · Audio

1Olúwa jẹ ọba, jẹ́ kí ayé kí ó yọ̀ 2Ojú ọ̀run àti òkùnkùn yíká 3Iná ń jó níwájú rẹ̀. Ó sì ń jó àwọn ọ̀tá rẹ̀ yíkákiri. 4Ìmọ́lẹ̀ rẹ̀ tàn ó sì kárí ayé 5Òkè gíga yọ́ gẹ́gẹ́ bí ìda níwájú Olúwa, 6Àwọn ọ̀run ròyìn òdodo rẹ̀, gbogbo ènìyàn sì rí ògo rẹ̀. 7Gbogbo àwọn tí ń sin ère fínfín ni ojú yóò tì, 8Sioni gbọ́, inú rẹ̀ sì dùn Olúwa. 9Nítorí pé ìwọ, Olúwa, ni ó ga ju gbogbo ayé lọ 10Jẹ kí gbogbo àwọn tí ó fẹ́ Olúwa, kórìíra ibi, ó pa ọkàn àwọn ènìyàn mímọ́ rẹ̀ mọ́ 11Ìmọ́lẹ̀ tàn sórí àwọn olódodo 12Ẹ yọ̀ nínú Olúwa, ẹ̀yin tí ẹ jẹ́ olódodo,

已达到每日限制

升级您的计划以继续使用 AI 功能和更高的每日限制。

比较所有套餐 →