YOR 诗篇 章 57

诗篇 57

YOR · 比较 · Audio

1àánú fún mi, Ọlọ́run, ṣàánú fún mi, 2Mo kígbe sókè sí Ọlọ́run Ọ̀gá-ògo jùlọ, 3Òun yóò ránṣẹ́ láti ọ̀run wá, 4Mo wà ní àárín àwọn kìnnìún; 5Kí a yìn ọ́ Ọlọ́run, ju ọ̀run lọ, 6Wọ́n ti ta àwọ̀n sílẹ̀ fún ẹsẹ̀ mi: 7Ọkàn mi ti múra Ọlọ́run; 8Jí, ìwọ ọkàn mi! 9Èmi ó máa yìn ọ́, Olúwa, láàrín àwọn orílẹ̀-èdè; 10Nítorí títóbi ní ìfẹ́ rẹ, tí ó dé ọ̀run; 11Gbígbéga ni ọ́, Ọlọ́run, ju àwọn ọ̀run lọ;

已达到每日限制

升级您的计划以继续使用 AI 功能和更高的每日限制。

比较所有套餐 →