YOR 诗篇 章 144

诗篇 144

YOR · 比较 · Audio

1Ìyìn sí Olúwa àpáta mi, 2Òun ni Ọlọ́run ìfẹ́ mi àti odi alágbára mi, 3Olúwa, kí ni ènìyàn tí ìwọ fi ń ṣàníyàn fún un, 4Ènìyàn rí bí èmi; 5Tẹ ọ̀run rẹ ba, Olúwa, kí o sì sọ̀kalẹ̀; 6Rán mọ̀nàmọ́ná kí ó sì fọ́n àwọn ọ̀tá ká; 7Na ọwọ́ rẹ sílẹ̀ láti ibi gíga; 8Ẹnu ẹni tí ó kún fún èké 9Èmi yóò kọ orin tuntun sí ọ 10Òun ni ó fi ìgbàlà fún àwọn ọba, 11Gbà mí kí o sì yọ mí nínú ewu 12Kí àwọn ọmọkùnrin wa 13Àká wa yóò kún 14àwọn màlúù wa yóò ru ẹrù wúwo 15Ìbùkún ni fún àwọn ènìyàn náà tí ó wà ní irú ipò bẹ́ẹ̀, Olúwa ń ṣe.

已达到每日限制

升级您的计划以继续使用 AI 功能和更高的每日限制。

比较所有套餐 →