YOR 诗篇 章 16

诗篇 16

YOR · 比较 · Audio

1Pa mí mọ́, Ọlọ́run, 2Mo sọ fún Olúwa, “Ìwọ ni Olúwa mi, 3Sí àwọn ènìyàn tí ó wà ní ayé, 4Ìṣòro àwọn wọ̀n-ọn-nì yóò pọ̀ sí i, àní àwọn tí ń tọ ọlọ́run mìíràn lẹ́yìn. 5Olúwa, ni ìpín ìní mi tí mo yàn àti ago mi, 6Okùn ààlà ilẹ̀ ti bọ́ sí ọ̀dọ̀ mi ní ibi dídára; 7Èmi yóò yin Olúwa, ẹni tí ó gbà mí ní ìyànjú; 8Mo ti gbé Olúwa síwájú mi ní ìgbà gbogbo. 9Nítorí èyí, ọkàn mi yọ̀, ahọ́n mi pẹ̀lú ń fò fáyọ̀; 10nítorí ìwọ kò ní fi ọ̀kan sílẹ̀ nínú isà òkú, 11Ìwọ ti fi ipa ọ̀nà ìyè hàn mí;

已达到每日限制

升级您的计划以继续使用 AI 功能和更高的每日限制。

比较所有套餐 →