YOR 诗篇 章 121

诗篇 121

YOR · 比较 · Audio

1Èmi yóò gbé ojú mi sórí òkè wọ̀n-ọn-nì— 2Ìrànlọ́wọ́ mi tí ọwọ́ Olúwa wá, 3Òun kì yóò jẹ́ kí ẹsẹ̀ rẹ kí ó yẹ̀; 4Kíyèsi, ẹni tí ń pa Israẹli mọ́, 5Olúwa ni olùpamọ́ rẹ; Olúwa ní òjìji rẹ ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ. 6Oòrùn kì yóò pa ọ́ ní ìgbà ọ̀sán 7Olúwa yóò pa ọ́ mọ́ kúrò nínú ibi gbogbo 8Olúwa yóò pa àlọ àti ààbọ̀ rẹ mọ́

已达到每日限制

升级您的计划以继续使用 AI 功能和更高的每日限制。

比较所有套餐 →