YOR 诗篇 章 124

诗篇 124

YOR · 比较 · Audio

1Ìbá má ṣe pé Olúwa tí ó ti wà fún wa,” 2ìbá má ṣe pé Olúwa tó wà ní tiwa, 3nígbà náà ni wọn ò bá gbé wà mì láààyè 4nígbà náà ni omi 5nígbà náà ni agbéraga 6Olùbùkún ni Olúwa, tí kò fi wá fún wọ́n 7Ọkàn wa yọ bí ẹyẹ jáde kúrò nínú okùn apẹyẹ; 8Ìrànlọ́wọ́ wa ń bẹ ní orúkọ Olúwa,

已达到每日限制

升级您的计划以继续使用 AI 功能和更高的每日限制。

比较所有套餐 →