YOR 诗篇 章 12

诗篇 12

YOR · 比较 · Audio

1Ràn wá lọ́wọ́, Olúwa, nítorí ẹni ìwà-bí-Ọlọ́run kò sí mọ́; 2Olúkúlùkù ń parọ́ fún aládùúgbò rẹ̀; 3Kí Olúwa kí ó gé ètè èké wọn 4tí ó wí pé, 5“Nítorí ìnilára àwọn aláìlágbára àti ìkérora àwọn aláìní, Olúwa wí. 6Ọ̀rọ̀ Olúwa sì jẹ aláìlábùkù, 7Olúwa, ìwọ yóò pa wá mọ́ 8Àwọn ènìyàn búburú ń rin ìrìn fáàrí kiri

已达到每日限制

升级您的计划以继续使用 AI 功能和更高的每日限制。

比较所有套餐 →