YOR 诗篇 章 54

诗篇 54

YOR · 比较 · Audio

1Gbà mí, Ọlọ́run nípa orúkọ rẹ: 2Gbọ́ àdúrà mi, Ọlọ́run; 3Àwọn agbéraga àlejò dìde sí mí. 4Kíyèsi i Ọlọ́run ni olùrànlọ́wọ́ mi; 5Jẹ́ kí ibi padà sẹ́yìn sí àwọn tí ń sọ̀rọ̀ ìbàjẹ́ sí mi; 6Èmí yóò rú ẹbọ àtinúwá sí ọ, Olúwa, 7Nítorí tí ó yọ mí kúrò nínú ibi gbogbo

已达到每日限制

升级您的计划以继续使用 AI 功能和更高的每日限制。

比较所有套餐 →