YOR 诗篇 章 79

诗篇 79

YOR · 比较 · Audio

1lọ́run, àwọn orílẹ̀-èdè ti wá ilẹ̀ ìní rẹ; 2Wọn ti fi ara òkú àwọn ìránṣẹ́ rẹ 3Wọ́n tu ẹ̀jẹ̀ jáde gẹ́gẹ́ bí omi 4Àwa di ohun ẹ̀gàn sí àwọn tí ó yí wa ká, 5Nígbà wo, Olúwa? Ní ìwọ ó máa bínú títí láé? 6Tú ìbínú rẹ jáde sí orílẹ̀-èdè 7nítorí wọ́n ti run Jakọbu 8Má ṣe ka ẹ̀ṣẹ̀ àwọn baba wa sí wa lọ́rùn 9Ràn wá lọ́wọ́, Ọlọ́run Olùgbàlà wa, 10Àwọn orílẹ̀-èdè yóò máa wí pé, 11Jẹ́ kí ìmí ẹ̀dùn oǹdè náà wá síwájú rẹ, 12San án padà sí àyà àwọn aládùúgbò wa nígbà méje Olúwa. 13Nígbà náà àwa ènìyàn rẹ,

已达到每日限制

升级您的计划以继续使用 AI 功能和更高的每日限制。

比较所有套餐 →