YOR 诗篇 章 129

诗篇 129

YOR · 比较 · Audio

1Ìgbà púpọ̀ ni wọ́n ti pọ́n mi lójú 2“Ìgbà púpọ̀ ni wọ́n ti pọ́n mi lójú 3Àwọn awalẹ̀ walẹ̀ sí ẹ̀yìn mi: 4Olódodo ni Olúwa: 5Kí gbogbo àwọn tí ó kórìíra Sioni kí ó dààmú, 6Kí wọn kí ó dàbí koríko orí ilẹ̀ 7èyí tí olóko pípa kó kún ọwọ́ rẹ̀: 8Bẹ́ẹ̀ ni àwọn tí ń kọjá lọ kò wí pé, Olúwa kí ó pẹ̀lú yín: Olúwa.

已达到每日限制

升级您的计划以继续使用 AI 功能和更高的每日限制。

比较所有套餐 →