YOR 诗篇 章 59

诗篇 59

YOR · 比较 · Audio

1Gbà mí lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá à mi, Ọlọ́run; 2Gbà mí lọ́wọ́ àwọn oníṣẹ́ búburú 3Wò ó, bí wọ́n ṣe ba ní bùba dè mí! Olúwa. 4Èmi kò ṣe àìṣedéédéé kan, síbẹ̀ wọ́n sáré wọ́n ṣetán láti kọlù mí. 5Olúwa Ọlọ́run Alágbára, Sela. 6Wọ́n padà ní àṣálẹ́, 7Kíyèsi ohun tí wọ́n tú jáde ní ẹnu: 8Ṣùgbọ́n ìwọ, Olúwa, yóò fi wọ́n rẹ́rìn-ín, 9Ìwọ agbára mi, èmi ó máa kọrin ìyìn sí ọ; 10Ọlọ́run àánú mi ni yóò ṣáájú mi. 11Ṣùgbọ́n má ṣe pa wọ́n, Olúwa asà wa, 12Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ ẹnu wọn, 13pa wọ́n run nínú ìbínú, Sela. 14Wọ́n padà ní àṣálẹ́, 15Wọ́n ń rin kiri fún oúnjẹ 16Ṣùgbọ́n èmi ó kọrin agbára rẹ, 17Ìwọ agbára mi, èmi ó kọrin ìyìn sí ọ;

已达到每日限制

升级您的计划以继续使用 AI 功能和更高的每日限制。

比较所有套餐 →