YOR 诗篇 章 70

诗篇 70

YOR · 比较 · Audio

1Yára, Ọlọ́run, láti gbà mí là, Olúwa, wá kánkán láti ràn mí lọ́wọ́. 2Kí àwọn tí ń wá ọkàn mi 3Kí a pa wọ́n ní ẹ̀yìn dà fún èrè 4Ṣùgbọ́n kí àwọn tí ó ń wá ọ ó máa yọ̀ 5Ṣùgbọ́n mo jẹ́ òtòṣì àti aláìní; Olúwa, má ṣe dúró pẹ́.

已达到每日限制

升级您的计划以继续使用 AI 功能和更高的每日限制。

比较所有套餐 →