YOR भजन संहिता अध्याय 92

भजन संहिता 92

1Ohun rere ni láti máa fi ọpẹ́ fún Olúwa 2láti kéde ìfẹ́ rẹ̀ ní òwúrọ̀ 3lára ohùn èlò orin olókùn mẹ́wàá 4Nítorí ìwọ ni ó mú inú mi dùn Olúwa; 5Báwo ni iṣẹ́ rẹ tí tóbi tó, Olúwa? 6Òpè ènìyàn kò mọ̀ ọ́n, 7nígbà tí àwọn ènìyàn búburú bá rú jáde bí i koríko 8Ṣùgbọ́n ìwọ Olúwa ni a ó gbéga títí láé. 9Nítorí nítòótọ́ àwọn ọ̀tá rẹ, Olúwa, 10Ìwọ ti gbé ìwo mi ga bí i ti màlúù igbó; 11Ojú mi ti rí ìṣubú àwọn ọ̀tá mi; 12Olódodo yóò gbèrú bí i igi ọ̀pẹ, 13tí a gbìn sí ilé Olúwa, 14Wọn yóò máa so èso ní ìgbà ogbó, 15láti fihàn pé, “Ẹni ìdúró ṣinṣin ni Olúwa;

दैनिक सीमा तक पहुंच गई

उच्च दैनिक सीमा के साथ AI सुविधाओं का उपयोग जारी रखने के लिए अपनी योजना को अपग्रेड करें।

सभी योजनाओं की तुलना करें →