भजन संहिता 44
1À ti fi etí wa gbọ́, Ọlọ́run; 2Ìwọ fi ọwọ́ rẹ lé orílẹ̀-èdè jáde, 3Kì í ṣe nípa idà wọn ni wọ́n gba ilẹ̀ náà, 4Ìwọ ni ọba àti Ọlọ́run mi, 5Nípasẹ̀ rẹ ni àwa ó bi àwọn ọ̀tá wa ṣubú; 6èmi kì yóò gbẹ́kẹ̀lé ọrun mi, 7ṣùgbọ́n ìwọ fún wa ní ìṣẹ́gun lórí àwọn ọ̀tá wa, 8Nínú Ọlọ́run àwa ń ṣògo ní gbogbo ọjọ́, Sela. 9Ṣùgbọ́n nísinsin yìí, ìwọ ti kọ̀ wá, ìwọ sì ti dójútì wá, 10Ìwọ ti bá wa jà, 11Ìwọ fi wá fún jíjẹ bí ẹran àgùntàn, 12Ìwọ ta àwọn ènìyàn rẹ fún owó kékeré, 13Ìwọ sọ wá di ẹni ẹ̀sín ní ọ̀dọ̀ àwọn aládùúgbò wa, 14Ìwọ ti sọ wá di ẹni ìfisọ̀rọ̀ láàrín àwọn orílẹ̀-èdè; 15Ìdójútì mi ń bẹ pẹ̀lú mi ní gbogbo ọjọ́, 16nítorí ọ̀rọ̀ ẹ̀gàn àti ọ̀rọ̀ ẹ̀tàn 17Gbogbo àwọn nǹkan wọ̀nyí ń ṣẹlẹ̀ sí wa, 18Ọkàn wa kò padà sẹ́yìn; 19Ṣùgbọ́n wọ́n kọlù wá, 20Bí àwa bá ti gbàgbé orúkọ Ọlọ́run wa 21Ǹjẹ́ Ọlọ́run kì yóò rí ìdí rẹ̀, 22Síbẹ̀, nítorí rẹ̀ àwa da àyà kọ ikú, ní ojoojúmọ́ 23Jí, Olúwa! Èéṣe tí ìwọ ń sùn? 24Èéṣe tí ìwọ ń pa ojú rẹ mọ́ 25Nítorí a tẹrí ọkàn wa ba sínú eruku; 26Dìde kí o sì ràn wá lọ́wọ́;