YOR भजन संहिता अध्याय 101

भजन संहिता 101

1Èmi yóò kọrin ìfẹ́ àti òdodo; Olúwa, èmi yóò máa kọrin ìyìn. 2Èmi yóò máa rin ìrìn mi pẹ̀lú ọgbọ́n láìlẹ́ṣẹ̀, 3Èmi kì yóò gbé ohun búburú sí iwájú mi: 4Agídí ọkàn yóò kúrò lọ́dọ̀ mi; 5Ẹnikẹ́ni tí ó bá ń sọ̀rọ̀ ẹnìkejì rẹ̀ ní ìkọ̀kọ̀, 6Ojú mi yóò wà lára àwọn olóòtítọ́ lórí ilẹ̀, 7Ẹni tí ó bá ń ṣe ẹ̀tàn, kì yóò gbé ilé mi, 8Ní ojoojúmọ́ ní èmi yóò wá máa pa a lẹ́nu mọ Olúwa.

दैनिक सीमा तक पहुंच गई

उच्च दैनिक सीमा के साथ AI सुविधाओं का उपयोग जारी रखने के लिए अपनी योजना को अपग्रेड करें।

सभी योजनाओं की तुलना करें →