YOR भजन संहिता अध्याय 42

भजन संहिता 42

1Bí àgbọ̀nrín ti ń mí hẹlẹ sí ipa odò omi, 2Òùngbẹ Ọlọ́run ń gbẹ ọkàn mi, fún Ọlọ́run alààyè. 3Oúnjẹ mi ni omijé mi 4Nígbà tí mo bá rántí nǹkan yìí, 5Èéṣe tí o fi ń rẹ̀wẹ̀sì, ìwọ ọkàn mi? 6Ọlọ́run mi, ọkàn mi ń rẹ̀wẹ̀sì nínú mi: 7Ibú omi ń pe ibú omi 8Ní ọ̀sán ní Olúwa ran ìfẹ́ rẹ̀, 9Èmi wí fún Ọlọ́run àpáta mi, 10Bí ẹni pé idà egungun mi ni ẹ̀gàn tí 11Èéṣe tí ìwọ fi ń rẹ̀wẹ̀sì, ìwọ ọkàn mi?

दैनिक सीमा तक पहुंच गई

उच्च दैनिक सीमा के साथ AI सुविधाओं का उपयोग जारी रखने के लिए अपनी योजना को अपग्रेड करें।

सभी योजनाओं की तुलना करें →