YOR भजन संहिता अध्याय 86

भजन संहिता 86

1Gbọ́, Olúwa, kí o sì dá mi lóhùn, 2Dáàbò bò ayé mi, nítorí a ti yà mí sọ́tọ̀ fún ọ: 3Ṣàánú fún mi, Olúwa, 4Mú ayọ̀ wà fún ìránṣẹ́ rẹ, Olúwa, 5Ìwọ ń dáríjì, ìwọ sì dára, Olúwa, 6Gbọ́ àdúrà mi, Olúwa; 7Ní ọjọ́ ìpọ́njú mi èmi yóò pè ọ́, 8Nínú àwọn òrìṣà kò sí ẹni tí ó dàbí i rẹ, Olúwa: 9Gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè tí ìwọ dá 10Nítorí pé ìwọ tóbi, ìwọ sì ń ṣe ohun ìyanu; 11Kọ́ mi ní ọ̀nà rẹ, Olúwa, 12Èmi ó yìn ọ́, Olúwa Ọlọ́run mi, pẹ̀lú gbogbo ọkàn mi; 13Nítorí títóbi ni ìfẹ́ rẹ si mi; 14Àwọn onígbèéraga ń dojúkọ mí, Ọlọ́run; 15Ṣùgbọ́n ìwọ, Olúwa, jẹ́ aláàánú àti Ọlọ́run olójúrere, 16Yípadà sí mi kí o sì ṣàánú fún mi; 17Fi àmì hàn mí fún rere, Olúwa

दैनिक सीमा तक पहुंच गई

उच्च दैनिक सीमा के साथ AI सुविधाओं का उपयोग जारी रखने के लिए अपनी योजना को अपग्रेड करें।

सभी योजनाओं की तुलना करें →