YOR भजन संहिता अध्याय 5

भजन संहिता 5

1Fi etí sí ọ̀rọ̀ mi, Olúwa, 2Fi etí sílẹ̀ sí igbe mi fún ìrànlọ́wọ́, 3Ní òwúrọ̀, Olúwa, ìwọ yóò gbọ́ ohùn mi; 4Nítorí ìwọ kì í ṣe Ọlọ́run tí ó ní inú dídùn sí búburú; 5Àwọn agbéraga kò le è dúró 6ìwọ yóò pa àwọn tí ń ṣe èké run. Olúwa yóò kórìíra. 7Ṣùgbọ́n èmi, nípa títóbi àánú rẹ̀, 8Tọ́ mi, Olúwa, nínú òdodo rẹ, 9Kò sí ọ̀rọ̀ kan ní ẹnu wọn tí a lè gbàgbọ́; 10Dá wọn lẹ́bi Ọlọ́run! 11Ṣùgbọ́n, jẹ́ kí gbogbo àwọn tí ó sádi ọ́ kí ó yọ̀; 12Dájúdájú, Olúwa, ìwọ bùkún olódodo;

दैनिक सीमा तक पहुंच गई

उच्च दैनिक सीमा के साथ AI सुविधाओं का उपयोग जारी रखने के लिए अपनी योजना को अपग्रेड करें।

सभी योजनाओं की तुलना करें →