YOR भजन संहिता अध्याय 26

भजन संहिता 26

1e ìdájọ́ mi, Olúwa, Olúwa, 2Wádìí mi wò, Ìwọ Olúwa, kí o sì dán mi wò, 3nítorí ìfẹ́ ẹ̀ rẹ tí ó dúró ṣinṣin ń bẹ níwájú mi, 4Èmi kò jókòó pẹ̀lú aláìṣòótọ́, 5Èmi ti kórìíra àwùjọ àwọn ènìyàn búburú 6Èmí ó wẹ ọwọ́ mi ní àìlẹ́ṣẹ̀, Olúwa. 7Èmi yóò kọrin sókè àní orin ọpẹ́, 8Háà Olúwa, èmí ń fẹ́ ilé rẹ níbi tí ìwọ ń gbé, 9Má ṣe gbá mi dànù pẹ̀lú àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀, 10àwọn tí ọwọ́ wọn kún fún ìwà ibi, 11Ṣùgbọ́n èmi ó máa rìn nínú ìwà títọ́; 12Ẹsẹ̀ mi dúró lórí ilẹ̀ tí ó tẹ́jú; Olúwa.

दैनिक सीमा तक पहुंच गई

उच्च दैनिक सीमा के साथ AI सुविधाओं का उपयोग जारी रखने के लिए अपनी योजना को अपग्रेड करें।

सभी योजनाओं की तुलना करें →