भजन संहिता 7
1Olúwa Ọlọ́run mi, ààbò mi wà nínú rẹ; 2kí wọn ó má ba à fa ọkàn mi ya gẹ́gẹ́ bí kìnnìún, 3Olúwa Ọlọ́run mi, tí èmi bá ṣe èyí 4bí èmi bá ṣe ibi sí ẹni tí ń wá àlàáfíà pẹ̀lú mi, 5nígbà náà, jẹ́ kí ọ̀tá mi lé mi kí wọn sì mú mi; Sela. 6Dìde, Olúwa, nínú ìbínú rẹ; 7Kí ìpéjọ àwọn ènìyàn yíká. 8Jẹ́ kí Olúwa ṣe ìdájọ́ àwọn ènìyàn. Olúwa, gẹ́gẹ́ bí òdodo mi, 9Ọlọ́run Olódodo, 10Ààbò mi ń bẹ lọ́dọ̀ Ọlọ́run, 11Ọlọ́run ni onídàájọ́ òtítọ́, 12Bí kò bá yípadà, 13Ó ti pèsè ohun ìjà ikú sílẹ̀; 14Ẹni tí ó lóyún ohun búburú, 15Ẹni tí ó gbẹ́ ọ̀fìn, tí ó kó o jáde 16Wàhálà tí ó fà padà sórí rẹ̀; 17Èmi ó fi ọpẹ́ fún Olúwa nítorí òdodo rẹ̀, Olúwa Ọ̀gá-ògo jùlọ.