YOR भजन संहिता अध्याय 115

भजन संहिता 115

1Kì í ṣe fún wa, Olúwa kì í ṣe fún wa, 2Torí kí ni àwọn kèfèrí yóò ṣe sọ pé, 3Ṣùgbọ́n Ọlọ́run wa wà lọ́run: 4Fàdákà òun wúrà ni èrè àwọn aláìkọlà, 5Wọ́n ní ẹnu, ṣùgbọ́n wọn kò le sọ̀rọ̀, 6Wọ́n ní etí, ṣùgbọ́n wọn kò fi gbọ́rọ̀: 7Wọ́n ní ọwọ́, ṣùgbọ́n wọn kò lò ó, 8Àwọn tí ń ṣe wọ́n dàbí wọn; 9Ìwọ Israẹli gbẹ́kẹ̀lé Olúwa: 10Ẹ̀ yin ilé Aaroni, gbẹ́kẹ̀lé Olúwa: 11Ẹ̀ yin tí ó bẹ̀rù Olúwa, gbẹ́kẹ̀lé Olúwa: 12Olúwa tí ń ṣe ìrántí wa; yóò bùkún ilé Israẹli; 13Ìbùkún ni fún àwọn tí ó bẹ̀rù Olúwa, 14Olúwa yóò mú ọ pọ̀ sí i síwájú àti síwájú, 15Ẹ fi ìbùkún fún Olúwa 16Ọ̀run àní ọ̀run ni ti Olúwa: 17Òkú kò lè yìn Olúwa, 18Ṣùgbọ́n àwa ó fi ìbùkún fún Olúwa Olúwa.

दैनिक सीमा तक पहुंच गई

उच्च दैनिक सीमा के साथ AI सुविधाओं का उपयोग जारी रखने के लिए अपनी योजना को अपग्रेड करें।

सभी योजनाओं की तुलना करें →