YOR भजन संहिता अध्याय 109

भजन संहिता 109

1lọ́run, ti èmi ń fi ìyìn fún, 2nítorí àwọn ènìyàn búburú àti ẹlẹ́tàn 3Wọ́n fi ọ̀rọ̀ ìríra yí mi káàkiri; 4Nípò ìfẹ́ mi, wọn ń ṣe ọ̀tá mi, 5Wọ́n sì fi ibi san ìre fún mi 6Yan àwọn ènìyàn búburú láti dojúkọ 7Kí a dá a lẹ́bi nígbà tí a bá ṣe ìdájọ́ 8Kí ọjọ́ rẹ̀ kí ó kúrú; 9Kí àwọn ọmọ rẹ̀ di aláìní baba 10Jẹ́ kí àwọn ọmọ rẹ̀ máa ṣagbe kiri 11Jẹ́ kí alọ́nilọ́wọ́gbà kí ó mú ohun gbogbo tí ó ní 12Má ṣe jẹ́ kí ẹnìkan ṣe àánú fún un 13Kí a gé àrọ́mọdọ́mọ rẹ̀ kúrò 14Kí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn baba rẹ̀ kí Olúwa. 15Jẹ́ kí ẹ̀ṣẹ̀ wọn kí ó wà ní ìrántí níwájú Olúwa 16Nítorí kò rántí láti ṣàánú, 17Ó fẹ́ràn láti máa mú ègún wá sí orí rẹ̀: 18Bí ó ti fi ègún wọ ará rẹ̀ láṣọ bí ẹ̀wù 19Jẹ́ kí ó rí fún un bí aṣọ tí a dà bò ó ní ara, 20Èyí ni èrè àwọn ọ̀tá mi láti ọwọ́ Olúwa wá; 21Ṣùgbọ́n ìwọ, ìwọ ṣe fún mi Olúwa Olódùmarè, 22Nítorí pé tálákà àti aláìní ni mí, 23Èmi ń kọjá lọ bí òjìji tí àṣálẹ́, 24Eékún mi di aláìlera nítorí àwẹ̀ gbígbà 25Mo dàbí ẹ̀gàn fún àwọn olùfisùn mi; 26Ràn mí lọ́wọ́, Olúwa Ọlọ́run mi; 27Jẹ́ kí wọn mọ̀ pé ọwọ́ rẹ ni èyí Olúwa, ni ó ṣe é. 28Wọ́n ó máa gégùn ún, ṣùgbọ́n ìwọ máa súre, 29Jẹ́ kí a wọ àwọn ọ̀tá mi ní aṣọ ìtìjú 30Pẹ̀lú ẹnu mi èmi yóò máa yin Olúwa gidigidi 31Nítorí ó dúró ní apá ọ̀tún aláìní

दैनिक सीमा तक पहुंच गई

उच्च दैनिक सीमा के साथ AI सुविधाओं का उपयोग जारी रखने के लिए अपनी योजना को अपग्रेड करें।

सभी योजनाओं की तुलना करें →