YOR भजन संहिता अध्याय 143

भजन संहिता 143

1Olúwa gbọ́ àdúrà mi, 2Má ṣe mú ìránṣẹ́ rẹ wá sí ìdájọ́, 3Ọ̀tá ń lépa mi, 4Nítorí náà ẹ̀mí mi ṣe rẹ̀wẹ̀sì nínú mi; 5Èmi rántí ọjọ́ tí ó ti pẹ́; 6Èmi na ọwọ́ mi jáde sí ọ: Sela. 7Dá mi lóhùn kánkán, Olúwa; 8Mú mi gbọ́ ìṣeun ìfẹ́ rẹ ní òwúrọ̀: 9Gbà mí kúrò lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá mi, Olúwa, 10Kọ́ mi láti ṣe ìfẹ́ rẹ, 11Nítorí orúkọ rẹ, Olúwa, sọ mi di ààyè; 12Nínú ìfẹ́ rẹ tí kì í kùnà, ké àwọn ọ̀tá mi kúrò,

दैनिक सीमा तक पहुंच गई

उच्च दैनिक सीमा के साथ AI सुविधाओं का उपयोग जारी रखने के लिए अपनी योजना को अपग्रेड करें।

सभी योजनाओं की तुलना करें →