YOR भजन संहिता अध्याय 140

भजन संहिता 140

1Olúwa, gbà mi lọ́wọ́ ọkùnrin búburú u nì, 2ẹni tí ń ro ìwà búburú ní inú wọn; 3Wọ́n ti pọ́n ahọ́n wọn bí ejò, 4Olúwa, pa mí mọ́ kúrò lọ́wọ́ àwọn ènìyàn búburú; 5Àwọn agbéraga ti dẹkùn sílẹ̀ fún mi àti okùn: 6Èmi wí fún Olúwa pé ìwọ ni Ọlọ́run mi; Olúwa, gbọ́ ohùn ẹ̀bẹ̀ mi. 7Olúwa Olódùmarè, agbára ìgbàlà mi, 8Olúwa, máa ṣe fi ìfẹ́ ènìyàn búburú fún un; Sela. 9Bí ó ṣe ti orí àwọn tí ó yí mi káàkiri ni, 10A ó da ẹ̀yin iná sí wọn lára, 11Má ṣe jẹ́ kí aláhọ́n búburú fi ẹsẹ̀ múlẹ̀ ní ayé; 12Èmi mọ̀ pé, Olúwa yóò mú ọ̀nà olùpọ́njú dúró, 13Nítòótọ́ àwọn olódodo yóò

दैनिक सीमा तक पहुंच गई

उच्च दैनिक सीमा के साथ AI सुविधाओं का उपयोग जारी रखने के लिए अपनी योजना को अपग्रेड करें।

सभी योजनाओं की तुलना करें →