YOR Isaiah Chương 64

Isaiah 64

YOR · So sánh · Âm thanh

1Ìwọ ìbá fa ọ̀run ya kí o sì sọ̀kalẹ̀ wá, 2Gẹ́gẹ́ bí ìgbà tí iná mú ẹ̀ka igi jó 3Nítorí nígbà tí o bá ṣe àwọn ohun ẹ̀rù tí àwa kò nírètí, 4Láti ìgbà àtijọ́ kò sí ẹni tí ó gbọ́ rí 5Ìwọ a máa wá fún ìrànlọ́wọ́ àwọn tí wọn 6Gbogbo wa ti dàbí ẹnìkan tí ó jẹ́ aláìmọ́, 7Ẹnikẹ́ni kò pe orúkọ rẹ 8Síbẹ̀síbẹ̀, Olúwa, ìwọ ni Baba wa. 9Má ṣe bínú kọjá ààlà, ìwọ Olúwa, 10Àwọn ìlú mímọ́ rẹ ti di aṣálẹ̀; 11Tẹmpili mímọ́ ológo wa, níbi tí àwọn baba wa ti yìn ọ́, 12Lẹ́yìn gbogbo nǹkan wọ̀nyí, Olúwa, ìwọ ó ha sì tún fi ara rẹ pamọ́ bí?

Đã đạt giới hạn hàng ngày

Nâng cấp gói của bạn để tiếp tục sử dụng các tính năng AI với giới hạn hàng ngày cao hơn.

So sánh tất cả các gói →