YOR Isaiah Chương 28

Isaiah 28

YOR · So sánh · Âm thanh

1Ègbé ni fún adé ìgbéraga, 2Kíyèsi i, Olúwa ní ẹnìkan tí ó le, tí ó sì lágbára, 3Adé ìgbéraga àwọn ọ̀mùtí Efraimu, 4Òdòdó tí ó ń rọ náà tí í ṣe ẹwà ògo rẹ̀, 5Ní ọjọ́ náà Olúwa àwọn ọmọ-ogun 6Òun yóò sì jẹ́ ẹ̀mí ìdájọ́ òdodo 7Àwọn wọ̀nyí pẹ̀lú ta gbọ̀nọ́ngbọ̀nọ́n fún ọtí wáìnì 8Gbogbo orí tábìlì ni ó kún fún èébì 9“Ta ni ẹni náà tí ó ń gbìyànjú àti kọ́? 10Nítorí tí í ṣe: báyìí ni orí, 11Ó dára báyìí, pẹ̀lú ètè àjèjì àti ahọ́n àìmọ̀ 12àwọn tí ó sọ fún wí pé, 13Fún ìdí èyí, ọ̀rọ̀ Olúwa sí wọn yóò di pé, 14Nítorí náà, ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ Olúwa, ẹ̀yin ẹlẹ́gàn, 15Ẹ fọ́n pé, “Àwa ti bá ikú mulẹ̀, 16Nítorí náà, báyìí ni Olúwa Olódùmarè wí: 17Èmi yóò fi ìdájọ́ ṣe okùn òsùwọ̀n 18Májẹ̀mú yín tí ẹ bá ikú dá ni a ó fa igi lé; 19Nígbàkígbà tí ó bá ti wá ni 20Ibùsùn kúrú púpọ̀ fún ìnara lé lórí, 21Olúwa yóò dìde sókè gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe 22Ní ìsinsin yìí ẹ dákẹ́ ẹlẹ́yà ṣíṣe, Olúwa, àní Olúwa àwọn ọmọ-ogun ti sọ fún mi 23Tẹ́tí kí o sì gbọ́ ohùn mi, 24Nígbà tí àgbẹ̀ kan bá tu ilẹ̀ láti gbìn 25Nígbà tí òun bá ti tẹ́ ojú ilẹ̀ rẹ̀ pẹrẹsẹ 26Ọlọ́run rẹ̀ tọ́ ọ ṣọ́nà 27Nítorí a kò fi ohun èlò ìpakà dili, 28A gbọdọ̀ lọ ìyẹ̀fun kí a tó ṣe àkàrà; 29Gbogbo èyí pẹ̀lú ti ọ̀dọ̀ Olúwa àwọn ọmọ-ogun wá,

Đã đạt giới hạn hàng ngày

Nâng cấp gói của bạn để tiếp tục sử dụng các tính năng AI với giới hạn hàng ngày cao hơn.

So sánh tất cả các gói →