YOR Isaiah Chương 40

Isaiah 40

YOR · So sánh · Âm thanh

1 tù ú nínú, ẹ tu ènìyàn mi nínú, 2Sọ̀rọ̀ pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́ fún Jerusalẹmu Olúwa 3Ohùn ẹni tí ń kígbe ní ijù: Olúwa ṣe, 4Gbogbo àfonífojì ni a ó gbé sókè, 5Ògo Olúwa yóò sì di mí mọ̀, Olúwa ni ó ti sọ ọ́.” 6Ohùn kan wí pé, “Kígbe sókè.” 7Koríko ń rọ ìtànná sì ń rẹ̀, Olúwa ń fẹ́ lù wọ́n. 8Koríko ń rọ ìtànná sì ń rẹ̀, 9Ìwọ tí o mú ìyìn ayọ̀ wá sí Sioni, 10Wò ó, Olúwa Olódùmarè náà ń bọ̀ wá pẹ̀lú agbára, 11Ó ń tọ́ àwọn agbo rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí olùṣọ́-àgùntàn: 12Ta ni ó tiwọn omi nínú kòtò ọwọ́ rẹ̀, 13Ta ni ó ti mọ ọkàn Olúwa, 14Ta ni Olúwa ké sí kí ó là á lọ́yẹ 15Nítòótọ́ àwọn orílẹ̀-èdè dàbí i ẹ̀kún omi nínú garawa; 16Lebanoni kò tó fún pẹpẹ iná, 17Níwájú rẹ̀ ni gbogbo orílẹ̀-èdè dàbí ohun tí kò sí; 18Ta ni nígbà náà tí ìwọ yóò fi Ọlọ́run wé? 19Ní ti ère, oníṣọ̀nà ni ó dà á, 20Ọkùnrin kan tí ó tálákà jù kí ó lè mú 21Ǹjẹ́ o kò tí ì mọ̀ 22Òun jókòó lórí ìtẹ́ ní òkè òbírí ilẹ̀ ayé, 23Ó sọ àwọn ọmọ ọba di asán 24Gẹ́rẹ́ tí a ti gbìn wọ́n, 25“Ta ni ẹ ó fi mi wé? 26Gbé ojú rẹ sókè kí o sì wo àwọn ọ̀run. 27Èéṣe tí o fi sọ, ìwọ Jakọbu? Olúwa; 28Ìwọ kò tí ì mọ̀? Olúwa òun ni Ọlọ́run ayérayé, 29Ó ń fi agbára fún àwọn aláàárẹ̀ 30Àní, ó ń rẹ̀ wọ́n àwọn ọ̀dọ́, wọ́n ń rẹ̀wẹ̀sì, 31ṣùgbọ́n àwọn tí ó gbẹ́kẹ̀lé Olúwa

Đã đạt giới hạn hàng ngày

Nâng cấp gói của bạn để tiếp tục sử dụng các tính năng AI với giới hạn hàng ngày cao hơn.

So sánh tất cả các gói →