YOR Isaiah Chương 47

Isaiah 47

YOR · So sánh · Âm thanh

1Sọ̀kalẹ̀, jókòó nínú eruku, 2Mú òkúta-ọlọ kí o sì lọ ìyẹ̀fun; 3Ìhòhò rẹ ni a ó sí síta 4Olùràpadà wa Olúwa àwọn ọmọ-ogun ni orúkọ rẹ̀ 5“Jókòó ní ìdákẹ́ jẹ́ẹ́, lọ sínú òkùnkùn, 6Inú bí mi sí àwọn ènìyàn mi 7Ìwọ wí pé, ‘Èmi yóò tẹ̀síwájú títí láé— 8“Nísinsin yìí, tẹ́tí sílẹ̀, ìwọ oníwọ̀ra ẹ̀dá 9Méjèèjì yìí ni yóò wá sórí rẹ 10Ìwọ ti ní ìgbẹ́kẹ̀lé nínú ìwà ìkà rẹ 11Ìparun yóò dé bá ọ 12“Tẹ̀síwájú nígbà náà, pẹ̀lú àfọ̀ṣẹ rẹ 13Gbogbo ìmọ̀ràn tí o ti gbà ni 14Lóòótọ́ wọ́n dàbí ìṣẹ́pẹ́ igi; 15Gbogbo ohun tí wọ́n lè ṣe fún ọ nìyìí

Đã đạt giới hạn hàng ngày

Nâng cấp gói của bạn để tiếp tục sử dụng các tính năng AI với giới hạn hàng ngày cao hơn.

So sánh tất cả các gói →