YOR Isaiah Chương 2

Isaiah 2

YOR · So sánh · Âm thanh

1Èyí ni ohun tí Isaiah ọmọ Amosi rí nípa Juda àti Jerusalẹmu. 2Ní ìgbẹ̀yìn ọjọ́ Olúwa ni a ó fi ìdí rẹ̀ kalẹ̀ 3Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ni yóò wá, wọn yóò sì wí pé, Olúwa, Olúwa láti Jerusalẹmu. 4Òun ó ṣe ìdájọ́ láàrín àwọn orílẹ̀-èdè, 5Wá, ẹ̀yìn ará ilé e Jakọbu, Olúwa. Olúwa 6Ìwọ ti kọ àwọn ènìyàn rẹ sílẹ̀, 7Ilẹ̀ wọn kún fún fàdákà àti wúrà, 8Ilẹ̀ ẹ wọn kún fún ère, 9Nítorí náà ni a ó ṣe rẹ ènìyàn sílẹ̀ 10Wọ inú àpáta lọ, Olúwa, 11Ojú agbéraga ènìyàn ni a ó rẹ̀ sílẹ̀ Olúwa nìkan ṣoṣo ni a ó gbéga ní ọjọ́ náà. 12Olúwa àwọn ọmọ-ogun ní ọjọ́ kan ní ìpamọ́ 13nítorí gbogbo igi kedari Lebanoni, tó ga tó rìpó 14nítorí gbogbo òkè gíga ńlá ńlá 15fún ilé ìṣọ́ gíga gíga 16fún gbogbo ọkọ̀ àwọn oníṣòwò 17Ìgbéraga ènìyàn ni a ó tẹ̀ lórí ba Olúwa nìkan ṣoṣo ni a ó gbéga ní ọjọ́ náà, 18gbogbo ère òrìṣà yóò pòórá. 19Àwọn ènìyàn yóò sálọ sínú ihò àpáta Olúwa 20Ní ọjọ́ náà ni àwọn ènìyàn yóò máa sọ 21Wọn yóò sálọ sínú ihò ìsàlẹ̀ àpáta Olúwa 22Dẹ́kun à ń gba ènìyàn gbọ́,

Đã đạt giới hạn hàng ngày

Nâng cấp gói của bạn để tiếp tục sử dụng các tính năng AI với giới hạn hàng ngày cao hơn.

So sánh tất cả các gói →