YOR Isaiah Chương 13

Isaiah 13

YOR · So sánh · Âm thanh

1̀rọ̀-ìmọ̀ tí ó kan Babeli èyí tí Isaiah ọmọ Amosi rí. 2Gbé àsíá sókè ní orí òkè gbẹrẹfu, 3Mo ti pàṣẹ fún àwọn ẹni mímọ́ mi, 4Gbọ́ ohùn kan ní àwọn orí òkè, Olúwa àwọn ọmọ-ogun ti kó ogun rẹ̀ jọ 5Wọ́n wá láti ọ̀nà jíjìn réré, Olúwa pẹ̀lú àwọn ohun ìjà ìbínú rẹ̀, 6Ẹ hu, nítorí ọjọ́ Olúwa súnmọ́ tòsí, 7Nítorí èyí, gbogbo ọwọ́ ni yóò rọ, 8Ẹ̀rù yóò gbá wọn mú, 9Kíyèsi i, ọjọ́ Olúwa ń bọ̀ 10Àwọn ìràwọ̀ ojú ọ̀run àti ìkójọpọ̀ wọn 11Èmi yóò jẹ ayé ní ìyà nítorí ibi rẹ̀, 12Èmi yóò jẹ́ kí ọkùnrin kí ó wọn 13Nítorí náà èmi yóò jẹ́ kí àwọn ọ̀run kí ó wárìrì; Olúwa àwọn ọmọ-ogun, 14Gẹ́gẹ́ bí egbin tí à ń dọdẹ rẹ̀, 15Ẹnikẹ́ni tí a bá gbámú ni a ó wọ́ nílẹ̀ tuurutu, 16Àwọn ọ̀dọ́mọdé wọn ni a ó fọ́ sí wẹ́wẹ́ níṣojú wọn, 17Kíyèsi i, èmi yóò ru àwọn Media sókè sí wọn, 18Ọrùn wọn yóò ré àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin lulẹ̀; 19Babeli, ohun ọ̀ṣọ́ àwọn ìjọba 20A kì yóò tẹ̀ ibẹ̀ dó mọ́ 21Ṣùgbọ́n àwọn ẹranko igbó ni yóò dùbúlẹ̀ níbẹ̀, 22Ìkookò yóò máa gbó ní ibùba wọn,

Đã đạt giới hạn hàng ngày

Nâng cấp gói của bạn để tiếp tục sử dụng các tính năng AI với giới hạn hàng ngày cao hơn.

So sánh tất cả các gói →