YOR Isaiah Chương 22

Isaiah 22

YOR · So sánh · Âm thanh

1̀rọ̀-ìmọ̀ tí ó jẹ mọ́ àfonífojì ìran. 2Ìwọ ìlú tí ó kún fún rúkèrúdò, 3Gbogbo àwọn olórí i yín ti jùmọ̀ sálọ; 4Nítorí náà ni mo wí pé, “Yípadà kúrò lọ́dọ̀ mi: 5Olúwa, Olúwa àwọn ọmọ-ogun ní ọjọ́ kan 6Elamu mú apó-ọfà lọ́wọ́, 7Àyànfẹ́ àfonífojì rẹ kún fún kẹ̀kẹ́ ogun, 8Gbogbo ààbò Juda ni a ti ká kúrò. 9Ìwọ rí i pé ìlú u Dafidi 10Ìwọ ka àwọn ilé tí ó wà ní Jerusalẹmu 11Ìwọ mọ agbemi sí àárín ògiri méjì 12Olúwa, àní Olúwa àwọn ọmọ-ogun, 13Ṣùgbọ́n wò ó, ayọ̀ àti ayẹyẹ wà; 14Olúwa àwọn ọmọ-ogun ti sọ èyí di mí mọ̀ létí ì mi: “Títí di ọjọ́ ikú yín a kò ní ṣe ètùtù fún ẹ̀ṣẹ̀ yìí,” ni Olúwa wí, àní Olúwa àwọn ọmọ-ogun. 15Èyí ni ohun tí Olúwa, àní Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí, 16Kí ni ohun tí ò ń ṣe níhìn-ín yìí àti pé 17“Kíyèsára, Olúwa fẹ́ gbá ọ mú gírígírí 18Òun yóò ká ọ rúgúdù bí i òkìtì 19Èmi yóò yọ ọ́ kúrò ní ipò rẹ, 20“Ní ọjọ́ náà. Èmi yóò ké sí ọmọ ọ̀dọ̀ mi, Eliakimu ọmọ Hilkiah. 21Èmi yóò fi aṣọ rẹ wọ̀ ọ́, n ó sì so ẹ̀wọ̀n rẹ mọ́ ọn ní ọrùn, èmi ó sì gbé àṣẹ rẹ lé e lọ́wọ́. Òun yó sì jẹ́ baba fún gbogbo olùgbé e Jerusalẹmu àti fún ilé e Juda. 22Èmi yóò sì fi kọ́kọ́rọ́ ilé e Dafidi lé e ní èjìká; ohunkóhun tí ó bá ṣí, ẹnikẹ́ni kì yóò lè ti, ohunkóhun tí ó bá sì tì, ẹnikẹ́ni kì yóò le è ṣí. 23Èmi yóò sì kàn mọ́lẹ̀ bí èèkàn tí ó dúró gírígírí ní ààyè e rẹ̀; òun yóò sì jẹ́ ibùjókòó ọlá fún ilé baba rẹ̀. 24Gbogbo ògo ìdílé rẹ̀ ni wọn yóò sì fi kọ ní ọrùn: ìran rẹ̀ àti àrọ́mọdọ́mọ rẹ̀, gbogbo ohun èlò ife, títí dé orí ago ọtí. 25“Ní ọjọ́ náà,” ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí, “Èèkàn tí a kàn mọ́lẹ̀ gírígírí ní ààyè e rẹ̀ yóò yẹrí, yóò dẹ̀gbẹ́ yóò sì fẹ̀gbẹ́ lélẹ̀ àti ẹrù tí ó létéńté lórí i rẹ̀ ni a ó gé lulẹ̀.” Olúwa ni ó ti sọ ọ́.

Đã đạt giới hạn hàng ngày

Nâng cấp gói của bạn để tiếp tục sử dụng các tính năng AI với giới hạn hàng ngày cao hơn.

So sánh tất cả các gói →