YOR Psalm অধ্যায় 83

Psalm 83

1lọ́run, má ṣe dákẹ́; 2Wo bí àwọn ọ̀tá rẹ ti ń rọ́kẹ̀kẹ̀ lọ, 3Pẹ̀lú àrékérekè ni wọn dìtẹ̀ sí àwọn ènìyàn rẹ; 4Wọn wí pé, “wá, ẹ jẹ́ kí á pa wọ́n run bí orílẹ̀-èdè, 5Wọ́n gbìmọ̀ pọ̀ pẹ̀lú ọkàn kan; 6Àgọ́ Edomu àti ti àwọn ará Iṣmaeli, 7Gebali, Ammoni àti Amaleki, 8Asiria pẹ̀lú ti darapọ̀ mọ́ wọn Sela. 9Ṣe sí wọn bí ìwọ ti ṣe sí Midiani 10ẹni tí ó ṣègbé ní Endori 11Ṣe àwọn ọlọ́lá wọn bí Orebu àti Seebu, 12tí ó wí pé, “Ẹ jẹ́ kí a gbà ní ìní 13Ìwọ Ọlọ́run, ṣe wọ́n bí ààjà, 14Bí iná ti í jó igbó, 15bẹ́ẹ̀ ni kí o fi ẹ̀fúùfù líle rẹ lépa wọn 16Fi ìtìjú kún ojú wọn, Olúwa. 17Jẹ́ kí ojú kí ó tì wọ́n, kí wọ́n sì dààmú láéláé 18jẹ́ kí wọn mọ̀ pé ìwọ, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Olúwa:

দৈনিক সীমা পূর্ণ হয়েছে

উচ্চতর দৈনিক সীমা সহ AI বৈশিষ্ট্যগুলি ব্যবহার চালিয়ে যেতে আপনার পরিকল্পনা আপগ্রেড করুন।

সব প্ল্যান তুলনা করুন →