YOR Psalm অধ্যায় 66

Psalm 66

1 hó ìhó ayọ̀ sí Ọlọ́run, ẹ̀yin ilẹ̀ gbogbo! 2Ẹ kọrin ọlá orúkọ rẹ̀; 3Ẹ wí fún Ọlọ́run pé, “Ìwọ ti ní ẹ̀rù tó nínú iṣẹ́ rẹ! 4Gbogbo ayé ń wólẹ̀ fún ọ; Sela. 5Ẹ wá wo ohun tí Ọlọ́run ṣe, 6Ó yí òkun padà sí ilẹ̀ gbígbẹ, 7Ó ń jẹ ọba títí láé nípa agbára rẹ̀, Sela. 8Ẹ yin Ọlọ́run wa, ẹ̀yin ènìyàn, 9Ó ti dá ààbò bo ẹ̀mí wa, 10Nítorí ìwọ, Ọlọ́run, dán wa wò; 11Ìwọ mú wa wá sínú ẹ̀wọ̀n 12Ìwọ mú àwọn ènìyàn gún wá ní orí 13Èmi ó wá sí tẹmpili rẹ pẹ̀lú ọrẹ ẹbọ sísun, 14ẹ̀jẹ́ tí ètè mi jẹ́, tí ẹnu mi sì sọ 15Èmi ó rú ẹbọ sísun ọlọ́ràá sí ọ, Sela. 16Ẹ wá gbọ́ gbogbo ẹ̀yin tí ó bẹ̀rù Ọlọ́run; 17Mo fi ẹnu mi kígbe sókè sí i, 18Bí èmi bá gba ẹ̀ṣẹ̀ ní àyà mi, 19ṣùgbọ́n Ọlọ́run gbọ́ nítòótọ́ 20Ìyìn ni fún Ọlọ́run

দৈনিক সীমা পূর্ণ হয়েছে

উচ্চতর দৈনিক সীমা সহ AI বৈশিষ্ট্যগুলি ব্যবহার চালিয়ে যেতে আপনার পরিকল্পনা আপগ্রেড করুন।

সব প্ল্যান তুলনা করুন →