YOR Psalm অধ্যায় 138

Psalm 138

1Èmi yóò yìn ọ́ tinútinú mi gbogbo; 2Èmi ó máa gbàdúrà sí ìhà tẹmpili mímọ́ rẹ̀ 3Ní ọjọ́ tí mo ké pè é ọ́, ìwọ dá mi lóhùn, 4Gbogbo àwọn ọba ayé yóò yìn ọ́, Olúwa, ní ìgbà tí wọn bá gbọ́ ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ. 5Nítòótọ́, wọn ó máa kọrin ní ipa ọ̀nà Olúwa; Olúwa. 6Bí Olúwa tilẹ̀ ga, síbẹ̀ ó júbà àwọn onírẹ̀lẹ̀; 7Bí èmi tilẹ̀ ń rìn nínú ìpọ́njú ìwọ ni yóò sọ mi di ààyè; 8Olúwa yóò ṣe ohun tí ń ṣe tèmi láṣepé; Olúwa, àánú rẹ dúró láéláé;

দৈনিক সীমা পূর্ণ হয়েছে

উচ্চতর দৈনিক সীমা সহ AI বৈশিষ্ট্যগুলি ব্যবহার চালিয়ে যেতে আপনার পরিকল্পনা আপগ্রেড করুন।

সব প্ল্যান তুলনা করুন →