YOR Psalm অধ্যায় 60

Psalm 60

1Ìwọ ti kọ̀ wá sílẹ̀, 2Ìwọ ti mú ilẹ̀ wárìrì, ìwọ ti fọ́ ọ; 3Ìwọ ti fi ìgbà ewu han àwọn ènìyàn rẹ; 4Àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ̀, ní ìwọ fi ọ̀págun fún Sela. 5Fi ọwọ́ ọ̀tún rẹ gbà wá, kí o sì ràn wá lọ́wọ́, 6Ọlọ́run ti sọ̀rọ̀ láti ibi mímọ́ rẹ̀: 7Tèmi ni Gileadi, tèmi sì ni Manase; 8Moabu ní ìkòkò ìwẹsẹ̀ mi, 9Ta ni yóò mú mi wá sí ìlú olódi nì? 10Kì í ha ń ṣe ìwọ, Ọlọ́run, tí ó ti kọ̀ wá sílẹ̀ 11Fún wa ní ìrànlọ́wọ́ lórí àwọn ọ̀tá, 12Nípa Ọlọ́run ni a óò ní ìṣẹ́gun,

দৈনিক সীমা পূর্ণ হয়েছে

উচ্চতর দৈনিক সীমা সহ AI বৈশিষ্ট্যগুলি ব্যবহার চালিয়ে যেতে আপনার পরিকল্পনা আপগ্রেড করুন।

সব প্ল্যান তুলনা করুন →