YOR Psalm অধ্যায় 112

Psalm 112

1 fi ìyìn fún Olúwa. 2Irú-ọmọ rẹ̀ yóò jẹ́ alágbára ní ayé: 3Ọlá àti ọrọ̀ yóò wà nínú ilé rẹ̀; 4Fún olóòótọ́ ni ìmọ́lẹ̀ yóò tàn fún ní òkùnkùn: 5Ènìyàn rere fi ojúrere hàn, 6Dájúdájú a kì yóò le yí ní ipò padà láéláé: 7Òun kì yóò béèrè ìyìn búburú: Olúwa. 8Ó ti mú ọkàn rẹ̀ gbilẹ̀, ẹ̀rù kí yóò bà á, 9Ó ti pín ká, ó ti fi fún àwọn olùpọ́njú, 10Ènìyàn búburú yóò ri, inú wọn yóò sì bàjẹ́,

দৈনিক সীমা পূর্ণ হয়েছে

উচ্চতর দৈনিক সীমা সহ AI বৈশিষ্ট্যগুলি ব্যবহার চালিয়ে যেতে আপনার পরিকল্পনা আপগ্রেড করুন।

সব প্ল্যান তুলনা করুন →