YOR Psalm অধ্যায় 13

Psalm 13

1Yóò ti pẹ́ tó, Olúwa? Ìwọ o ha gbàgbé mi títí láé? 2Yóò ti pẹ́ tó tí èmi ó máa bá èrò mi jà, 3Wò mí kí o sì dá mi lóhùn, Olúwa Ọlọ́run mi. 4Ọ̀tá mi wí pé, “Èmi ti ṣẹ́gun rẹ̀,” 5Ṣùgbọ́n mo gbẹ́kẹ̀lé ìfẹ́ rẹ tí kì í kùnà; 6Èmi ó máa kọrin sí Olúwa,

দৈনিক সীমা পূর্ণ হয়েছে

উচ্চতর দৈনিক সীমা সহ AI বৈশিষ্ট্যগুলি ব্যবহার চালিয়ে যেতে আপনার পরিকল্পনা আপগ্রেড করুন।

সব প্ল্যান তুলনা করুন →