YOR Psalm অধ্যায় 41

Psalm 41

1Ìbùkún ni fún ẹni tí ó ń ro ti aláìní: Olúwa yóò gbà á ní ìgbà ìpọ́njú. 2Olúwa yóò dáàbò bò ó yóò sì pa ọkàn rẹ̀ mọ́: 3Olúwa yóò gbà á lórí àkéte àìsàn rẹ̀ 4Ní ti èmi, mo wí pé “Olúwa, ṣàánú fún mi; 5Àwọn ọ̀tá mi ń sọ̀rọ̀ mi nínú àrankàn, pé, 6Nígbàkígbà tí ẹnìkan bá wá wò mí, 7Àwọn ọ̀tá mi gbìmọ̀ papọ̀ nípa mi; 8wọ́n wí pé, “Ohun búburú ni ó dì mọ́ ọn ṣinṣin 9Pàápàá, ọ̀rẹ́ mi tímọ́tímọ́, ẹni tí mo gbẹ́kẹ̀lé, 10Ṣùgbọ́n ìwọ Olúwa, ṣàánú fún mi; 11Èmi mọ̀ pé inú rẹ̀ dùn sí mi, 12Bí ó ṣe tèmi ni 13Olùbùkún ni Olúwa, Ọlọ́run Israẹli,

দৈনিক সীমা পূর্ণ হয়েছে

উচ্চতর দৈনিক সীমা সহ AI বৈশিষ্ট্যগুলি ব্যবহার চালিয়ে যেতে আপনার পরিকল্পনা আপগ্রেড করুন।

সব প্ল্যান তুলনা করুন →