YOR Proverbs Chương 30

Proverbs 30

YOR · So sánh · Âm thanh

1Àwọn ọ̀rọ̀ Aguri ọmọ Jake, ọ̀rọ̀ ìsọtẹ́lẹ̀ tí ọkùnrin yìí sọ fún Itieli. 2“Èmi ni aláìmòye ju nínú àwọn ènìyàn; 3Èmi kò tilẹ̀ kọ́ ọgbọ́n 4Ta ni ó ti gòkè lọ sí ọ̀run tí ó sì padà sọ̀kalẹ̀? 5“Gbogbo ọ̀rọ̀ Ọlọ́run jẹ́ aláìlábùkù; 6Má ṣe fi kún ọ̀rọ̀ rẹ̀, 7“Ohun méjì ni mo ń béèrè lọ́wọ́ rẹ, Olúwa; 8Mú èké ṣíṣe àti irọ́ jìnnà sí mi; 9Àìṣe bẹ́ẹ̀, mo lè ní àníjù kí n sì gbàgbé rẹ Olúwa?’ 10“Má ṣe ba ìránṣẹ́ lórúkọ jẹ́ lọ́dọ̀ ọ̀gá rẹ̀, 11“Àwọn kan wá ṣépè fún àwọn baba wọn 12Àwọn tí ó mọ́ ní ojú ara wọn 13àwọn ẹni tí ojú wọn gbéga nígbà gbogbo, 14Àwọn ẹni tí eyín wọn jẹ́ idà 15“Eṣúṣú ni ọmọbìnrin méjì. 16Ibojì, inú tí ó yàgàn, 17“Ojú tí ń fi baba ṣẹ̀fẹ̀, 18“Àwọn nǹkan mẹ́ta wà tí ó jẹ́ ìyàlẹ́nu fún mi, 19ipa ẹyẹ idì ní òfúrufú 20“Èyí ni ọ̀nà alágbèrè obìnrin 21“Lábẹ́ nǹkan mẹ́ta ni ilé ayé ti ń wárìrì 22Ìránṣẹ́ tí ó di ọba 23obìnrin tí gbogbo ènìyàn kórìíra tí ó sì wá lọ́kọ 24“Àwọn ohun mẹ́rin ló kéré láyé 25Àwọn èèrà jẹ́ aláìlágbára ẹ̀dá, 26Ehoro jẹ́ aláìlágbára ẹ̀dá; 27àwọn eṣú kò ní ọba, 28Ọmọnílé fi ọwọ́ rẹ̀ dì mú, 29“Àwọn ohun mẹ́ta ní ń bẹ tí ń rìn rere, 30Kìnnìún, alágbára láàrín ẹranko tí kì í sá fún ohunkóhun 31Ẹsin tí a dì lẹ́gbẹ̀ẹ́; 32“Bí ìwọ bá ti hùwà aṣiwèrè nípa gbígbé ara rẹ ga, 33Nítorí bí fífún omi ọmú tí í mú wàrà wá,

Đã đạt giới hạn hàng ngày

Nâng cấp gói của bạn để tiếp tục sử dụng các tính năng AI với giới hạn hàng ngày cao hơn.

So sánh tất cả các gói →