YOR Proverbs Chương 17

Proverbs 17

YOR · So sánh · Âm thanh

1Òkèlè gbígbẹ tòun tàlàáfíà àti ìdákẹ́ jẹ́ẹ́ sàn 2Ọlọ́gbọ́n ìránṣẹ́ yóò ṣàkóso adójútini ọmọ, 3Iná ni a fi fọ́ fàdákà àti wúrà, Olúwa ló ń dán ọkàn wò. 4Ènìyàn búburú ń tẹ́tí sí ètè tí ń sọ ibi; 5Ẹnikẹ́ni tí ó bá sín olùpọ́njú jẹ, ó gan Ẹlẹ́dàá rẹ̀, 6Ọmọ ọmọ ni adé orí arúgbó, 7Ọ̀rọ̀ dídùn kò yẹ aṣiwèrè, 8Òkúta iyebíye jẹ́ ẹ̀bùn ní ojú ẹni tí ó ni í, 9Ẹni tí ó fojú fo ẹ̀ṣẹ̀ tí wọ́n ṣẹ̀ ẹ́ mú kí ìfẹ́ gbòòrò sí i. 10Ọ̀rọ̀ ìbáwí dun olóye ènìyàn 11Orí kunkun ni ènìyàn ìkà máa ń ṣe, 12Ó sàn kí ènìyàn pàdé beari tí a ti kó lọ́mọ 13Bí ènìyàn kan bá fi ibi san ìre, 14Bíbẹ̀rẹ̀ ìjà dàbí ẹni tí ó dá ojú fún adágún omi; 15Gbígbé ẹ̀bi fún aláre àti dídá ẹni jàre lẹ́bi, Olúwa kórìíra méjèèjì. 16Kí ni ìwúlò owó lọ́wọ́ aṣiwèrè, 17Ọ̀rẹ́ a máa fẹ́ni nígbà gbogbo, 18Ènìyàn aláìgbọ́n ṣe ìbúra, 19Ẹni tí ó fẹ́ràn ìjà fẹ́ràn ẹ̀ṣẹ̀; 20Ènìyàn aláyídáyidà ọkàn kì í gbèrú, 21Láti bí aláìgbọ́n lọ́mọ a máa fa ìbànújẹ́ ọkàn, 22Ọkàn tí ó túká jẹ́ oògùn gidi, 23Ènìyàn búburú a gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ ní ìkọ̀kọ̀ 24Olóye ènìyàn gbójú wo ọgbọ́n níwájú, 25Aṣiwèrè ọmọ mú ìbànújẹ́ bá baba rẹ̀ 26Kò dára láti fìyà jẹ ènìyàn tí kò ṣẹ̀, 27Ènìyàn tó ní ìmọ̀ máa ń ṣọ́ra fún àwọn ọ̀rọ̀ tí ó ń sọ, 28Kódà aláìgbọ́n máa ń dàbí ọlọ́gbọ́n bí ó bá dákẹ́,

Đã đạt giới hạn hàng ngày

Nâng cấp gói của bạn để tiếp tục sử dụng các tính năng AI với giới hạn hàng ngày cao hơn.

So sánh tất cả các gói →