YOR Proverbs Chương 20

Proverbs 20

YOR · So sánh · Âm thanh

1lẹ́yà ni ọtí wáìnì, aláriwo sì ní ọtí líle; 2Ìbẹ̀rù ọba dàbí kíké e kìnnìún; 3Iyì ni ó jẹ́ fún ènìyàn láti sá fún ìjà, 4Ọ̀lẹ kì í ṣiṣẹ́ oko nígbà tí ó yẹ, 5Ète ọkàn ènìyàn dàbí omi jíjìn; 6Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ni wọ́n máa ń sọ pe àwọn ní ìfẹ́ àìṣẹ̀tàn, 7Olódodo ènìyàn a máa gbé ìgbé ayé àìlábùkù 8Nígbà tí ọba bá jókòó sórí ìtẹ́ rẹ̀ láti ṣe ìdájọ́ 9Ta ni ó le è wí pé, “Mo ti ṣe ọkàn mi ní mímọ́, 10Ìwọ̀n èké àti òsùwọ̀n ìrẹ́jẹ Olúwa kórìíra méjèèjì. 11Kódà a mọ ọmọdé nípa iṣẹ́ rẹ̀ 12Etí tí ó ń gbọ́ àti ojú tí ó ń ríran Olúwa ni ó dá méjèèjì. 13Má ṣe fẹ́ràn oorun, àìṣe bẹ́ẹ̀ ìwọ yóò di tálákà. 14“Kò dára, kò dára!” ní ẹni tó ra ọjà máa ń wí; 15Wúrà wà, iyùn sì wà rẹpẹtẹ, 16Gba abọ́ ẹni tí ó ṣe onídùúró fún àlejò; 17Oúnjẹ tí a fi ọ̀nà èrú rí máa ń dùn lẹ́nu ènìyàn, 18Pa ètè rẹ mọ́ nípa wíwá ìmọ̀ràn 19Olófòófó a máa tú àṣírí 20Bí ènìyàn kan bá ṣépè fún baba tàbí ìyá rẹ̀, 21Ogún tí a kójọ kíákíá ní ìbẹ̀rẹ̀ 22Má ṣe wí pé, “N ó sẹ̀san àṣìṣe rẹ yìí fún ọ.” Olúwa yóò sì gbà ọ́ là. 23Olúwa kórìíra òdínwọ̀n èké. 24Olúwa ni ó ń ṣe olùdarí ìgbésẹ̀ ènìyàn. 25Ìdẹ̀kùn ni fún ènìyàn láti ṣe ìlérí kíákíá 26Ọlọ́gbọ́n ọba tú ènìyàn búburú ká; 27Àtùpà Olúwa ń ṣe àwárí ẹ̀mí ènìyàn 28Ìfẹ́ àti òdodo pa ọba mọ́, 29Ògo àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin ni agbára wọn, 30Ìgbájú ìgbámú àti ìfarapa máa ń mú ibi lọ,

Đã đạt giới hạn hàng ngày

Nâng cấp gói của bạn để tiếp tục sử dụng các tính năng AI với giới hạn hàng ngày cao hơn.

So sánh tất cả các gói →