Proverbs 16
1Ti ènìyàn ni ìgbèrò inú ọkàn Olúwa ni ìdáhùn ahọ́n ti ń wá. 2Gbogbo ọ̀nà ènìyàn ni ó dàbí i pé ó dára lójú ara rẹ̀ Olúwa ló ń díwọ̀n èrò inú ọkàn. 3Fi ohun gbogbo tí o bá ṣe lé Olúwa lọ́wọ́, 4Olúwa ti ṣe ohun gbogbo láti mú kí ó rí bí ó ṣe fẹ́ 5Olúwa kórìíra gbogbo ẹni tí ń gbéraga lọ́kàn rẹ̀ 6Nípasẹ̀ ìfẹ́ àti òtítọ́ a ṣe ètùtù ẹ̀ṣẹ̀ Olúwa ènìyàn sá fún ibi. 7Nígbà tí ọ̀nà ènìyàn bá tẹ́ Olúwa lọ́rùn, 8Ó sàn kí ó kéré pẹ̀lú òdodo 9Ènìyàn a máa pète ọ̀nà ara rẹ̀ lọ́kàn an rẹ̀ Olúwa ní í pinnu ìgbésẹ̀ rẹ̀. 10Ètè ọba a máa sọ̀rọ̀ nípa àṣẹ sí i 11Òdínwọ̀n àti òsùwọ̀n òtítọ́ wá láti ọ̀dọ̀ Olúwa; 12Àwọn ọba kórìíra ìwà àìtọ́ 13Àwọn ọba ní inú dídùn sí ètè tí ń ṣọ òtítọ́, 14Ìránṣẹ́ ikú ni ìbínú ọba jẹ́ 15Nígbà tí ojú ọba bá túká, ó túmọ̀ sí ìyè; 16Ó ti dára tó láti ní ọgbọ́n ju wúrà lọ 17Òpópó ọ̀nà àwọn ẹni dídúró ṣinṣin yàgò fún ibi, 18Ìgbéraga ní í ṣáájú ìparun, 19Ó sàn láti jẹ́ onírẹ̀lẹ̀ ọkàn láàrín àwọn olùpọ́njú 20Ẹnikẹ́ni tí ó bá tẹ̀lé ẹ̀kọ́ yóò rí ìre, Olúwa. 21Àwọn tí ó gbọ́n nínú ọkàn là ń pè ní olóye 22Òye jẹ́ orísun ìyè fún àwọn tí ó ní i, 23Ọkàn ọlọ́gbọ́n ènìyàn a máa ṣọ́ ẹnu rẹ̀ 24Ọ̀rọ̀ ìtura dàbí afárá oyin 25Ọ̀nà kan tí ó dàbí i pé ó dára lójú ènìyàn 26Ọkàn alágbàṣe ń ṣiṣẹ́ fún ara rẹ̀; 27Ènìyàn búburú ń pète 28Aláyídáyidà ènìyàn dá ìjà sílẹ̀ 29Oníjàgídíjàgan ènìyàn tan aládùúgbò rẹ̀ 30Ẹni tí ń ṣẹ́jú ń pètekéte; 31Adé ògo ni ewú orí jẹ́, 32Ó sàn láti jẹ́ onísùúrù ju ajagun ènìyàn lọ, 33A ṣẹ́ kèké si ìṣẹ́po aṣọ, Olúwa.