YOR Proverbs Chương 21

Proverbs 21

YOR · So sánh · Âm thanh

1kàn ọba ń bẹ lọ́wọ́ Olúwa; 2Gbogbo ọ̀nà ènìyàn dàbí i pé ó dára lójú rẹ̀, Olúwa ló ń díwọ̀n ọkàn. 3Ṣíṣe ohun tí ó dára tí ó sì tọ̀nà Olúwa ju ẹbọ lọ. 4Ojú tí ó gbéga àti ọkàn ìgbéraga, 5Ètè àwọn olóye jásí èrè 6Ìṣúra tí a kójọ nípasẹ̀ ahọ́n tí ń parọ́ 7Ìwà ipá àwọn ènìyàn búburú yóò wọ́ wọn lọ, 8Ọ̀nà ẹlẹ́ṣẹ̀ kún fún ìwà ẹ̀ṣẹ̀ 9Ó sàn láti máa gbé ní kọ̀rọ̀ orí òrùlé 10Ènìyàn búburú ń fẹ́ ibi 11Nígbà tí a bá ń fìyà jẹ ẹlẹ́gàn, 12Olódodo ṣàkíyèsí ilé ènìyàn búburú 13Ẹnikẹ́ni tí ó bá ti di etí rẹ̀ sí igbe olùpọ́njú, 14Ọ̀rẹ́ ìkọ̀kọ̀, mú ìbínú kúrò: 15Ayọ̀ ni fún olódodo láti ṣe ìdájọ́: 16Ẹni tí ó bá yà kúrò ní ọ̀nà òye, 17Ẹni tí ó bá fẹ́ afẹ́, yóò di tálákà: 18Ènìyàn búburú ni yóò ṣe owó ìràpadà fún olódodo, 19Ó sàn láti jókòó ní aginjù ju pẹ̀lú 20Ìṣúra iyebíye àti òróró wà ní ibùgbé ọlọ́gbọ́n; 21Ẹni tí ó bá tẹ̀lé òdodo àti àánú yóò rí ìyè, 22Ọlọ́gbọ́n gòkè odi ìlú àwọn alágbára, 23Ẹnikẹ́ni tí ó bá pa ẹnu àti ahọ́n rẹ̀ mọ́, 24Agbéraga àti alágídí ènìyàn ń gan orúkọ ara rẹ̀ nítorí ó ń hùwà nínú ìwà ìgbéraga rẹ̀, 25Ẹlẹ́rìí èké yóò ṣègbé, àwọn tí ó gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ̀ yóò parun láé; 26Ó ń fi ìlara ṣe ojúkòkòrò ní gbogbo ọjọ́: 27Ẹbọ ènìyàn búburú, ìríra ni: 28Ẹlẹ́rìí èké yóò ṣègbé: 29Ènìyàn búburú mú ojú ara rẹ̀ le: 30Kò sí ọgbọ́n, kò sí ìmòye, Olúwa. 31A ń múra ẹṣin sílẹ̀ de ọjọ́ ogun: Olúwa.

Đã đạt giới hạn hàng ngày

Nâng cấp gói của bạn để tiếp tục sử dụng các tính năng AI với giới hạn hàng ngày cao hơn.

So sánh tất cả các gói →