YOR Salmos Capítulo 89

Salmos 89

YOR · Comparar · Áudio

1Èmi kọrin títóbi ìfẹ́ Olúwa títí láé; 2Èmi ó wí pé, ìfẹ́ rẹ dúró títí láé, 3Ìwọ wí pé, “Èmi ti dá májẹ̀mú pẹ̀lú àwọn àyànfẹ́ mi 4‘Èmi ó fi ìdí irú-ọmọ rẹ múlẹ̀ títí láé 5Àwọn ọ̀run yóò máa yin iṣẹ́ ìyanu rẹ, Olúwa, 6Ta ni ó wà ní ọ̀run tí a lè fiwé Olúwa? Olúwa? 7Nínú àjọ ìgbìmọ̀ ẹni mímọ́, wọ́n bẹ̀rù Ọlọ́run gidigidi; 8Olúwa Ọlọ́run alágbára, ta ló dàbí rẹ Olúwa, òtítọ́ rẹ sì yí ọ ká. 9Ìwọ ń darí ríru omi Òkun; 10Ìwọ ni ó ti ya Rahabu pẹ́rẹpẹ̀rẹ 11Tìrẹ ní àwọn ọ̀run, ayé pẹ̀lú jẹ́ tìrẹ: 12Gúúsù àti àríwá ìwọ ni ó dá wọn; 13Ìwọ ní apá agbára; 14Òdodo àti òtítọ́ ni ìpìlẹ̀ ìtẹ́ rẹ: 15Ìbùkún ni fún àwọn ènìyàn tí wọn mọ ohùn ayọ̀ nì, Olúwa wọ́n ó máa rìn ní ìmọ́lẹ̀ ojú rẹ. 16Wọn ń ṣògo nínú orúkọ rẹ̀ ní gbogbo ọjọ́, 17Nítorí ìwọ ni ògo agbára wọn; 18Nítorí ti Olúwa ni asà wa, 19Nígbà náà ni ìwọ sọ̀rọ̀ nínú ìran, sí àwọn olóòtítọ́ rẹ, wí pé, 20Èmi ti rí Dafidi ìránṣẹ́ mi; 21Ìgbà gbogbo ni ọwọ́ mi yóò máa wà pẹ̀lú rẹ̀ 22Àwọn ọ̀tá kì yóò borí rẹ̀, 23Èmi yóò run àwọn ọ̀tá rẹ níwájú rẹ 24Òtítọ́ mi àti ìdúró ṣinṣin ìfẹ́ yóò wà pẹ̀lú rẹ 25Èmi ó gbé ọwọ́ rẹ lórí òkun, 26Òun yóò kígbe sí mi pé, ‘Ìwọ ni baba mi, Ọlọ́run mi, àti àpáta ìgbàlà mi!’ 27Èmi yóò ṣe é ni àkọ́bí mi, 28Títí láé ni èmi yóò pa ìfẹ́ dídúró ṣinṣin mọ́ fún un, 29Èmi ó fi ìdí irú-ọmọ rẹ̀ múlẹ̀ títí láé, 30“Bí àwọn ọmọ rẹ̀ bá kọ òfin mi sílẹ̀ 31Tí wọn bá ba ìlànà mi jẹ́ 32nígbà náà ni èmi ó fì ọ̀gọ̀ bẹ ìrékọjá wọn wò; 33ṣùgbọ́n èmi kò ní mú ìfẹ́ mi tí ó dúró ṣinṣin kúrò lọ́dọ̀ rẹ, 34Èmi kì yóò sẹ́ májẹ̀mú mi, 35Lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo ni èmi ti fi ìwà mímọ́ mi búra; 36Irú-ọmọ rẹ yóò dúró títí láé, 37A ó fi múlẹ̀ títí láé bí òṣùpá, Sela. 38Ṣùgbọ́n nísinsin yìí ìwọ ti ṣá tì, ìwọ sì kórìíra; 39Ìwọ ti sọ májẹ̀mú ìránṣẹ́ rẹ di òfo; 40Ìwọ ti wó gbogbo àwọn odi rẹ̀ 41Àwọn tí ń kọjá lọ fi ṣe ìjẹ; 42Ìwọ ti gbé ọwọ́ ọ̀tún ọ̀tá rẹ̀ sókè; 43Pẹ̀lú, ìwọ ti yí ojú idà rẹ̀ padà, 44Ìwọ ti mú ògo rẹ̀ kùnà, 45Ìwọ ti gé ọjọ́ èwe rẹ̀ kúrú; 46Yóò ti pẹ́ tó, Olúwa? 47Rántí bí ọjọ́ mi ti kúrú tó 48Ta ni yóò wà láààyè tí kò ní rí ikú rẹ̀? 49Olúwa, níbo ni ìṣeun ìfẹ́ rẹ àtijọ́ wà, 50Rántí, Olúwa, bí a ti ń gan àwọn ìránṣẹ́ rẹ; 51ẹ̀gàn tí àwọn ọ̀tá rẹ gàn, Olúwa, 52Olùbùkún ní Olúwa títí láé.

Limite Diário Atingido

Atualize seu plano para continuar usando recursos de IA com limites diários mais altos.

Comparar todos os planos →