YOR Salmos Capítulo 71

Salmos 71

YOR · Comparar · Áudio

1Nínú rẹ, Olúwa, ni mo ní ààbò; 2Gbà mí kí o sì tú mi sílẹ̀ nínú òdodo rẹ; 3Jẹ́ àpáta ààbò mi, 4Gbà mí, Ọlọ́run mi, lọ́wọ́ àwọn olùṣe búburú, 5Nítorí ìwọ jẹ́ ìrètí mi, Olúwa Olódùmarè, 6Mo gbẹ́kẹ̀lé ọ láti ìgbà ìbí mi; 7Mo di àmì fún ọ̀pọ̀ ènìyàn, 8Ìyìn rẹ̀ kún ẹnu mi, 9Má ṣe ta mí nù ní ọjọ́ ogbó mi, 10Nítorí àwọn ọ̀tá mi ń sọ̀rọ̀-òdì sí mi, 11Wọ́n wí pé, “Ọlọ́run ti kọ̀ ọ́ sílẹ̀; 12Má ṣe jìnnà sí mi, Ọlọ́run; 13Jẹ́ kí wọn kí ó dààmú, 14Ṣùgbọ́n ní tèmi, ìgbà gbogbo ní ìrètí mi; 15Ẹnu mi yóò sọ nípa ti òdodo rẹ, 16Èmi ó wá láti wá kéde agbára, Olúwa Olódùmarè; 17Láti ìgbà èwe, Ọlọ́run ni ìwọ ti kọ́ mi 18Pẹ̀lúpẹ̀lú, nígbà tí èmi di arúgbó tán tí mo sì hewú, 19Ọlọ́run, òdodo rẹ dé ọ̀run, 20Pẹ̀lúpẹ̀lú ìwọ ti mú mi rí ìdààmú, tí ó pọ̀ tí ó sì korò, 21Ìwọ yóò fi kún ọwọ́ mi 22Èmi yóò fi dùùrù mi yìn 23Ètè mi yóò kígbe fún ìyìn 24Ahọ́n mi yóò sọ ti òdodo rẹ ní gbogbo ọjọ́,

Limite Diário Atingido

Atualize seu plano para continuar usando recursos de IA com limites diários mais altos.

Comparar todos os planos →