YOR Salmos Capítulo 31

Salmos 31

YOR · Comparar · Áudio

1Nínú rẹ̀, Olúwa ni mo ti rí ààbò; 2Tẹ́ etí rẹ sí mi, 3Ìwọ pàápàá ni àpáta àti ààbò mi, 4Yọ mí jáde kúrò nínú àwọ̀n tí wọ́n dẹ pamọ́ fún mi, 5Ní ọwọ́ rẹ ni mo fi ẹ̀mí mi lé; Olúwa, Ọlọ́run òtítọ́. 6Èmi ti kórìíra àwọn ẹni tí ń fiyèsí òrìṣà tí kò níye lórí; Olúwa. 7Èmi yóò yọ̀, inú mi yóò dùn nínú ìfẹ́ ńlá rẹ, 8Pẹ̀lú, ìwọ kò sì fà mi lé àwọn ọ̀tá lọ́wọ́ 9Ṣàánú fún mi, ìwọ Olúwa, nítorí mo wà nínú ìpọ́njú; 10Èmi fi ìbànújẹ́ lo ọjọ́ mi 11Èmi di ẹni ẹ̀gàn láàrín àwọn ọ̀tá mi gbogbo, 12Èmi ti di ẹni ìgbàgbé kúrò ní ọkàn gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó ti kú; 13Nítorí mo gbọ́ ọ̀rọ̀ ẹ̀gàn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìpayà tí ó yí mi ká; 14Ṣùgbọ́n èmí gbẹ́kẹ̀lé ọ, ìwọ Olúwa; 15Ìgbà mi ń bẹ ní ọwọ́ rẹ; 16Jẹ́ kí ojú rẹ kí ó tan ìmọ́lẹ̀ sí ìránṣẹ́ rẹ lára; 17Má ṣe jẹ́ kí ojú ki ó tì mí, Olúwa; 18Jẹ́ kí àwọn ètè irọ́ kí ó dákẹ́ jẹ́ẹ́, 19Báwo ni títóbi oore rẹ̀ ti pọ̀ tó, 20Ní abẹ́ ìbòòji iwájú rẹ ni ìwọ pa wọ́n mọ́ sí 21Olùbùkún ni Olúwa, 22Èmí ti sọ nínú ìdágìrì mi, 23Ẹ fẹ́ Olúwa, gbogbo ẹ̀yin ènìyàn rẹ̀ mímọ́! Olúwa pa olódodo mọ́, 24Jẹ́ alágbára, yóò sì mú yín ní àyà le Olúwa.

Limite Diário Atingido

Atualize seu plano para continuar usando recursos de IA com limites diários mais altos.

Comparar todos os planos →