YOR Salmos Capítulo 127

Salmos 127

YOR · Comparar · Áudio

1Bí kò ṣe pé Olúwa bá kọ́ ilé náà Olúwa bá pa ìlú mọ́, olùṣọ́ jí lásán. 2Asán ni fún ẹ̀yin ti ẹ dìde ní kùtùkùtù 3Kíyèsi i, àwọn ọmọ ni ìní Olúwa: 4Bí ọfà ti rí ní ọwọ́ alágbára, 5Ìbùkún ni fún ọkùnrin náà tí apó rẹ̀ kún fún wọn;

Limite Diário Atingido

Atualize seu plano para continuar usando recursos de IA com limites diários mais altos.

Comparar todos os planos →