YOR Salmos Capítulo 36

Salmos 36

YOR · Comparar · Áudio

1Ìré-òfin-kọjá ènìyàn búburú 2Nítorí pé wọ́n pọ́n ara wọn ní ojú ara wọn 3Ọ̀rọ̀ ẹnu wọn ni ẹ̀ṣẹ̀ òhun ẹ̀tàn; 4Wọ́n gbìmọ̀ ìwà ìkà nígbà tí wọ́n wà lórí ibùsùn wọn: 5Ìdúró ṣinṣin ìfẹ́ rẹ, ìwọ Olúwa, ó ga dé ọ̀run, 6Òdodo rẹ dàbí àwọn òkè Ọlọ́run, Olúwa. 7Báwo ni ìṣeun ìdúró ṣinṣin ìfẹ́ rẹ ti tó! Ọlọ́run! 8Àsè ilé rẹ yóò tẹ́ wọn lọ́rùn gidigidi; 9Nítorí pé pẹ̀lú rẹ ni orísun ìyè wà: 10Mú ìṣeun ìfẹ́ ẹ̀ rẹ sí àwọn tí ó mọ̀ ọ́n 11Má ṣe jẹ́ kí ẹsẹ̀ agbéraga kí ó wá sí orí mi, 12Níbẹ̀ ni àwọn oníṣẹ́ ẹ̀ṣẹ̀ gbé ṣubú sí:

Limite Diário Atingido

Atualize seu plano para continuar usando recursos de IA com limites diários mais altos.

Comparar todos os planos →