Salmos 105
1Ẹ fi ọpẹ́ fún Olúwa, ké pe orúkọ rẹ̀, 2Kọrin sí i, kọrin ìyìn sí i; 3Ṣògo nínú orúkọ mímọ́ rẹ̀, Olúwa kí ó yọ̀. 4Wá Olúwa àti ipá rẹ̀; 5Rántí àwọn ìyanu tí ó ti ṣe, 6ẹ̀yin ìran Abrahamu ìránṣẹ́ rẹ̀, 7Òun ni Olúwa Ọlọ́run wa: 8Ó rántí májẹ̀mú rẹ̀ láéláé, 9májẹ̀mú tí ó dá pẹ̀lú Abrahamu, 10Ó ṣe ìdánilójú u rẹ̀ fún Jakọbu gẹ́gẹ́ bí àṣẹ, 11“Fún ìwọ ni èmi ó fún ní ilẹ̀ Kenaani 12Nígbà tí wọn kéré níye, 13wọ́n rìn kiri láti orílẹ̀-èdè sí orílẹ̀-èdè, 14Kò gba ẹnikẹ́ni láààyè láti pọ́n wọn lójú; 15“Má ṣe fọwọ́ kan ẹni àmì òróró mi; má sì ṣe wòlíì mi níbi.” 16Ó pe ìyàn sórí ilẹ̀ náà 17Ó sì rán ọkùnrin kan síwájú wọn 18Wọn fi ṣẹ́kẹ́ṣẹkẹ̀ bọ ẹsẹ̀ rẹ̀ 19títí ọ̀rọ̀ tí ó sọtẹ́lẹ̀ fi ṣẹ Olúwa fi dá a láre. 20Ọba ránṣẹ́ lọ tú u sílẹ̀ 21Ó fi jẹ olúwa lórí ilẹ̀ rẹ̀, 22gẹ́gẹ́ bí ìfẹ́ rẹ̀, kí ó máa 23Israẹli wá sí Ejibiti; 24Olúwa, sì mú àwọn ọmọ rẹ̀ bí sí i 25Ó yí wọn lọ́kàn padà láti kórìíra àwọn ènìyàn 26Ó rán Mose ìránṣẹ́ rẹ̀, 27Wọ́n ń ṣe iṣẹ́ ìyanu láàrín wọn 28Ó rán òkùnkùn, o sì mú ilẹ̀ ṣú 29Ó sọ omi wọn di ẹ̀jẹ̀, 30Ilẹ̀ mú ọ̀pọ̀lọ́ jáde wá, 31Ó sọ̀rọ̀, onírúurú eṣinṣin sì dìde, 32Ó sọ òjò di yìnyín, 33Ó lu àjàrà wọn àti igi ọ̀pọ̀tọ́ wọn 34Ó sọ̀rọ̀, eṣú sì dé, 35wọn sì jẹ gbogbo ewé ilẹ̀ wọn, 36Nígbà náà, ó kọlu gbogbo àwọn ilẹ̀ wọn, 37Ó mú Israẹli jáde 38Inú Ejibiti dùn nígbà tí wọn ń lọ, 39Ó ta àwọsánmọ̀ fún ìbòrí, 40Wọn béèrè, ó sì mú ẹyẹ àparò wá, 41Ó sì la àpáta, ó sì mú omi jáde; 42Nítorí ó rántí ìlérí mímọ́ rẹ̀ 43Ó sì fi ayọ̀ mú àwọn ènìyàn rẹ̀ jáde 44Ó fún wọn ní ilẹ̀ ìní náà, 45kí wọn kí ó lè máa pa àṣẹ rẹ̀ mọ́ Olúwa.