YOR 시편 장 98

시편 98

YOR · 비교 · 오디오

1 kọrin tuntun sí Olúwa, 2Olúwa ti sọ ìgbàlà rẹ̀ di mí mọ̀ 3Ó rántí ìfẹ́ rẹ̀ àti òtítọ́ rẹ̀ fún àwọn ará ilé Israẹli; 4Ẹ hó ìhó ayọ̀ sí Olúwa, gbogbo ayé, 5ẹ fi dùùrù kọrin sí Olúwa, pẹ̀lú dùùrù àti ìró ohùn orin mímọ́, 6pẹ̀lú ìpè àti fèrè Olúwa ọba. 7Jẹ́ kí òkun kí ó hó pẹ̀lú gbogbo 8Ẹ jẹ́ kí odo kí ó ṣápẹ́, 9ẹ jẹ́ kí wọn kọrin níwájú Olúwa,

일일 한도 도달

플랜을 업그레이드하여 더 높은 일일 한도로 AI 기능을 계속 사용하세요.

모든 요금제 비교 →